Primary4 Yoruba Scheme of Work
Primary 4 Yoruba scheme of work is designed to immerse young learners in the rich and vibrant Yoruba language and culture. Through engaging lessons, students will develop skills in speaking, reading, and writing Yoruba, while also exploring Yoruba traditions, folklore, and customs. By the end of the year, students will have a deeper appreciation for the Yoruba heritage and a stronger connection to their cultural roots.
Primary4 Yoruba Scheme of Work Download
Stay Informed: Know Your Responsibilities as an Educator
Download the Lagos State Unified Scheme of Work for Primary4 Yoruba below.

Primary 4 First Term Scheme of Work for Yoruba Language
| Yoruba Scheme of Work for Primary/Basic 4 | ||
| CLASS | Primary/Basic 4 | |
| SUBJECT | Yoruba | |
| TERM | First Term | |
| WEEK | TOPICS | Learning Objectives |
| 1 | Idånwö rånpe fun Ibere Såå tuntun | Idånwö rånpe fun Ibere Såå tuntun |
| 1Ede | Önkå åtisorö Yorübå | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le i. Salaye iye féresé to wå ninu yårå ikåwé ii. So itumo onka ati ati isoro lede Yorübå iii. Ka onka lati 0okan fifi dé ogoji. |
| Asa | Iwa Omoluabi | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le i. Sålåyé iwå omoluabi B.a. ‘lbåwi, ikinni, igbowofagba, siso otito, hihu iwa pele abi ii. Kiko orin iwå omoluabi kan Bi åpeere: Je Omo Rere- ii. Dåruko åwon iwå ibåje låwüjo, bi 0le jija, iro pipa, iwå ijinigbe, Ipaniyan, iwå jägiijägan, abbi. |
| Lit | Kika Iwe Itan Aroso: Ayänfe omo ôrukän. | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le i. ka iwe literaso ni akagbadun ii. Fa äwon kóko inú itan náä yo iii. Säläyé äwon iwä ědě inú’iwé na. |
| 2Ede | Apeko Pipe oro oniisilébů méji, méta, m’erin äti márůnún | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le i. Ka äwon oro apeko tó wä Iójú pátákó ikowe ti äpeere: oro onisillebu méji, m’eta, meran abbi. ii. pin si owoowo lati sagbeyewo awon oro apeko iii. Ko oro onisilebu merin ati márůn-ún |
| Asa | Eko äti sise ilé láwůjo Yorůbá | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le i. Dárúko orisi ise ilé sise n’ilě Yorůbá. B.a: aso fifo, ile gbigbá, ata lilo, abbi. ii. Säläyé äwon onä ti ä ó gbä se ämúlö’eko ile, bi ikini, ibowo fâgba, ltoJu ile, abbi. iii. Se ere onîse kekere ti Ó sâfihăn eko-ile. |
| Lit | Klka’iwe Lîtireso ti ijoba yan | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le: i. Fa âwon koko oro tó suyo ninu itan na. ii. Sâlăye âwon ti o wâ nînó ăwon literaso alohunwon yî (B.a isinję, imura idan pâpa) |
| 3Ede | Ami ldamo n’inó girama (Apă kinni) | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le: i. Salaye itumo âti idamo ninu giramâ ii. Dăruko orisi ămi idamo ati łwulo okookan won b.a. Ami idânudóró(.) Amii Iyanu (!), âmi ibeere(?) âmi Semi Koloonu(;) âmi kolonu(:) ami akamo onigun, ammi akamo oroto abi. |
| Asa | Aså’igbéyåwo n’ile Yorübå | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le: i. Sålåyé’itumo igbéyåwo nile Yorübå ii. Dåruko orisi igbéyåwo ti owå (b.a. ‘igbéyåwö ibile, sosi, masalaasi ati koöti) iii. Salaye awon igbése ti o wåyé ninu igbéyåwo. bi åpeere: ifojusode, Ijohen, itooro abbi. |
| Lit | Kika iwe Aroso: Ayanfe Omo Örukån. | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le: i. Ka iwé litiréso ni åkågbådun ii. Fa åwon koko inu itån nåå yo iii. Salaye awon iwå ödé inu iwe nåå. |
| 4Ede | Ifesiwaju nipa Armi idamo ninü g’iråmå | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le: i. Sålåyé årmi’idåmo ninu giramå åpeere ii. Ami åyolo komå oloke onibeji(” “), ami aopo (-), ami akamo(). ii. ohka si awon ami to se pataki ti won ma n gbeyin oro ninu gbolohun iii. se idamo won ninu gbolohun nipa sise awon ise won yi |
| Asa | Anfani iwa omoluabi ninu ile ati awujo | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le i. se ere nise to gbe iwa omoluabi han ii. won ko orin to jemo iwa omoluabi iii. piran si owoowo lati salaye anfaani iwa omoluabi iv. toka si ihuwasi akeeko to safihan iwa omoluabi |
| Lit | Eya Literaso | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le i. salaye ohun ti literaso je ii. daruko orisi eya lireraso lede yoruba iii. salaye pataki awon eya awon literaso won yi |
| 5Ede | Ohka ati Isiro Yoruba låti ogoji – ogorun-un | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le i.Ka onka lati ogoji dé ogorün-un ii.Töka bl onka se ri lé ati din. iii. Ka iye åga ijoko ni kilååsl |
| Asa | Igbéyåwo åti åwon ohun idåna | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le: i. Salåyé pataki ohun Idåna nibi Igbéyåwo ii. Daruko orisi awon ohun idana bi isu, obim ataare, orobi abi. iii. salaye ihulo awon ohun idana nibi igbeyawo |
| Lit | Itesiwaju lori ohu ti literaso je | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le i. Se alaye kikun nipa eya literaso yoruba ii. daruko ona ti wan pin si -Alohun ati apileko: Alohun pin si ewi, ere onise ati itan aroso -Literaso apinleko pin si: Itan aroso oloro geere, ewi apileko, ere onitan apileko |
| 6Ede | Isori oro lede yoruba | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le: i. fun isori oro ni oriki ii. daruko isori oro lede yoruba Bi apere: oro oruko, oro ise, oro apejuwe, oro aponle. iii. salaye ipaa ti okookan ko ati iwulo wan ninu gbolohun ede yoruba |
| Asa | Iwulo eko-ile ati ise ele | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le i. Jirorö nipa åwon ise ilé ii. såläyé påtåki ikini åti iböwofågbå Iéwüjo iii. Dåruko åwon önå ti a n lo lati toju ayika wa. |
| Lit | Kika Iwé ewi ipileko | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le: i. Da ka Iwé nåå fun ra won ni Iyårå ikéköö ii. sålåyé åwon åså åti ise Yorubå ti o suyo ninü Iwe litirese åpileko |
| 7 | Idanwo ranpe Ibewo / Isinmi ìdajì saa | Idanwo ranpe Ibewo / Isinmi ìdajì saa |
| 8Ede | Aroko kiko | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le: i.So oriki àroko ii.Salaye llanà àti ogbôn ti a n ta fun àròko kiko iii.So orisirisi aroko ti o wa. Bi àpeere, àròko alapèjuwe, oniròyìn, alalàyé, abbl. |
| Asa | Iwà Omoluàbi (Ere ti o fi ìwa omoluàbi hàn) | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le: i.Sàpejuwe ìwà omoluabi ii. Se àrojinle lor;i ìwà omoluàbi iii. Se ere onise to da Iori ìwa omoluabi lawujo |
| Lit | Kika ewi ÄpilekQ. OBINRIN NI MI | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le i. Ka/ko ewi to da Iori oblnrin ii. så!åyé påtåki obinrin Iåwujo |
| 9Ede | Arokq Asapejuwe Oünje ti mo férån | Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le i. sålåyé iru årokö ti a n pe ni aroko asapejuwe ii. Jiroro nipa åwon ohun iii. Ko aroko asapéjuwe lori ori ti won yan |
| Asa | Afiwé Igbéyawo ibile åti Igbéyäwö söösi åti massalasi | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le i. Jiroro nipa ijora laarin igbeyawo ibile åti Igbéyäwö söösi åti massalasi ii. salaye ipa awon igbeyawo yi lawujo iii. tooka si iyato laarin igbeyawo ibile, söösi åti massalasi iv. salaye ipa awon igbeyewo yii lawujo |
| Lit | Kika ewi apileko ti ijobâ yân | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le i. Le ka itân inu iwe naa ii. Tumo âwon oro ti o ta köko. iii. Jıroro nıpa âwon onâ-ede iv. Dâhûn âwon ıbeere ti o’ jeyo |
| 10Ede | Âpeko – oro Onİsilebu merin, mârun-un atimefa | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Ko âwon oro onısılebu marun, rrıârün lâti ojü pâtâko İkowe ii. Ko apeko awon oro ti oluko pe fün won. Bı apeere:: Aânu, Adeboye, Kâbiyâsi, Ajântaâla, Arİkuyerİ, abbi. |
| Asa | Äfiwé Igbéyåwo kootü, soosi ati Måsalaasi | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Sålåyé kikin nipa påtåki Igbéyåwö Köotu, soosi ati Måsalaasi ii. Dåruko ilåna to rö må Igbéyåwo yi iii. Jirörö nipa Iyåtö Iåårin åwon Igbéyawo nåa. |
| Lit | Ewi apileko lori eniyän ni ml | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i.Sålåyé kikin nipa ohun ti éniyån ii. Ko orin enikéni ti ba’ nipa fe Irånlöwö fun’ ii. Dahun Ibeere ni abala yii. |
| 11 | Atunyewo awon ise Saå yi | Atunyewo awon ise Saå yi |
| 12 | lgbâradi fün İdânwo saâ kini | lgbâradi fün İdânwo saâ kini |
| 13 | Idanwo saa kin-ın-ni | Idanwo saa kin-ın-ni |
Primary 4 Second Term Scheme of Work for Yoruba Language
| CLASS | Primary/Basic 4 | |
| SUBJECT | Yoruba | |
| TERM | Second Term | |
| WEEK | TOPICS | Learning Objectives |
| 1Ede | Idanwo ranpe fun ibeere Saa Keji | Idanrawo Ranpe fun ibere såå keji i. Äwon akekoo mu gbogbo åwon ékö ti won ti ko ni såå ti o kojå wa Si iranti won |
| Asa | Atünyewo ise saa kiini lori ede, asa ati litireso. | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:: i.rånti åwon eko ateyinwa ii. jiroro lori ohun ti o ye won ninu eko éteyinwa iii. beeré ohun ti ko ye won iv. dåhün ibééré Iori åkori eko |
| Lit | Atünyewo ise saa kiini lori ede, asa ati litireso. | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i.rånti åwon eko ateyinwa ii. jiroro lori ohun ti o ye won ninu eko éteyinwa iii. beeré ohun ti ko ye won iv. dåhün ibééré Iori åkori eko |
| 2Ede | Oro ati idakeji | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. so Itumö oro åti idåkeji ii. salaye bi Idakeji oro sen wåyé ii. Lo oro ati idakeji ni gbolohün kåkåni iv. fa ilå si abé åwon oro tö jé idåkeji sira won. |
| Asa | Ilu lilu | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Ki oriki ilu ni soki ii. Darüko orisi Ilu ile Yorubå. iii. Salåyé iwülo ilu lilü lawujo wa |
| Lit | Älo pipa | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Fun alo ni oriki alo tin alo n je ii. Dåruko orisi alo to wa iii. Sålåyé iwülo ålo. |
| 3Ede | Oruko osu nini odün | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Sålåyé åwon osu to wa ninu odün ii. Daruko åwon oruko osu naa iii. Rånti åwon ohun to se påtåki ninu awon naa iv. Se åmulo oruko naa ledé Yoruba |
| Asa | Ilu ati iwulo re | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Sålåyé åwon ilu ti n alü fün onså köokan ii. Dåråko åwon ti å lü nibi ayeye iii. Jirdrd nipa ijo ati orin ti å ko nibi ilü kökan. iv. So bi a se lé fi soro |
| Lit | Ålö Äpagbé | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Fün ålö åpagbé ni oriki ii. Se äkojo ålo onittan/åpagbé iii. Fa eko ninu ålö köokan yo. |
| 4Ede | Awon ojo ose ni ede Yorüba | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Dåruko åwon ojo to wa ninu ose. ii. So bi a nsee pe awon ojo wonyi iii. Salåye Idi/itan to ro mo awon ojo wonyi iv. Jiroro nipa igbagbo Yorüba nipa åwon ojo wonyi |
| Asa | Orisii ijo ti å n jo si ilu kookan | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Såpéjuwe bi a fe ri gbowo ijo lati ba ilü mu# ii. Salaye bi a ee Ie gbese låti bå mu iii. Se åpeere kikün Iori bi å se 1o gbö ilu. |
| Lit | Arofé Kikå | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Sålåyé kikon nipa oriki arofö ii. so nipa bi a gbohun soke sodo ninu arofo iii. Jiroro nipa koko ti o jeyo ninu arofo. |
| 5Ede | Ona ti an gbe se ibeere | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Daruko àwon a n gba se ìbeere ii Sàlàyé lekunrerë nipa awon wunren ôsegbere. ii. Se oniruuru apeere èrë a;òbéèrò, |
| Asa | Iwulo ilu lilù nilë Yorùba | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Salaye bi kòkan se ri ni ìrisi ati àpèjuwe ii. Daruko àwon ìlù, iii. Safaye awon ohun ti ari lo ìlù fin. iv. Dahùn àwon ìbéèrò lori eko yi |
| Lit | itesìwaju eko Iori arofe gigùn | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i Salaye ohun ti arofo je ii. Se akojopo orisi àròfo. iii, Fa àwon koko inu àròfè yo. iv. Ka àròfò jade. |
| 6Ede | Âwon onà ti à n gbà se ìbeere | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Sàlàyé nipa ìmò àteyìnwé ii. Darüko àwon atôka wunren asebeere. iii. lo awon wunr en atoka asebeere ni gbolohûn. |
| ASa | iwülo ìlu lilu Iawùjo Yoruba | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Sàlàyé pataki ilu lilu lawûjo wa ii. Daruko isê ti ilu n se, bi àpeere: Idârayâ, ìtüfò, ogun, iii. Âayé kikün lori awon koko. |
| Lit | Itan Akonilogbon | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Salaye awon itan akonilogbon ii. So nipa awon ogbon towa ninu itan iii. Fa awon eko inu itan yo iv. Jiroro nipa awon koko inu itan |
| 7 | Idanwo ranpe Ibewo / Isinmi ìdajì saa | Idanwo ranpe Ibewo / Isinmi ìdajì saa |
| 8Ede | Akanlo Ede | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Fun akanlo ede ni oriki ii. Se atoju akalo ede iii. Wa itumo si awon akanlo ede iv. Lo awon akalo ede ni gbolohun v. Salaye iwulo akanlo ede |
| Asa | Aso wiwo laarin okünrin | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Salaye/daruko awon aso wiwo laarin okunrin. ii. Pin aso si Isori mejl: iwole ati imurode iii. Jiroro nipa iyatö låårin aso iwole ati imurode iv. Rånti påtåki aso wiwö. v. Dahun Ibeere Iori ekö |
| Lit | Äröfo Iori iwå rere | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Salaye ki ni iwå rere. |
| 9Ede | Itesiwéjü ninå oro åti idäkeji | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Salaye Imö ati ateyinwa ii. Se åkojo orö ati idåkeji won iii, Lo åwon oro wonyi ni gbolohun. iv. So itumo åwon oro naa. |
| Asa | Oruko Abiso | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. So itumo oriki oruko abiso ii. Se akijopo oriki abiso iii. Salaye okookan oriki abiso iv. jiroro nipa pataki oriki abiso |
| Lit | Iwe kika Akaye | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Ka iwe literaso yi fun ran won ni iyara ikawe fun etigbo awon elegoo ati elegbe won ii. Salaye awon koko ti ibi ti won ka da lori iii. Wa itumo si awon oro tuntun ti o suyo nibi ti wan ka iv. Dahun ibeere lori ibi ti won ka naa |
| 10Ede | Aroso Akotan tabi oniroyin | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Fun owe ni oriki ii. Daruko orisirisi owe to wa iii. Se atikoju awon owe iv. Salaye ohun tin alo owe fun |
| Asa | Imura löde-öni | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Salaye onå imura låyé ode-oni ii. Dåruko åwon orisirisi aso ode-oni. Bi åpeere Seeti, Gåün. iii. Äfiwé aso åtijö åti ode-oni iv. Wiwa onå åbéyo si isoro aso wiwo Iode oni |
| Lit | Alo Apamö | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Sålåyé nipa ålö apamo. ii. Se åkpjo alo apamo iii. Jiroro nipa koko in ålö åpamo. iv. So iwülo ålo apamo. v. Dåhun ibéeré ti o je |
| 11 | Agbeyewo ise saa keji Iori Edé, Äså ati Litirésö Yorübå | Agbeyewo ise saa keji Iori Edé, Äså ati Litirésö Yorübå |
| 12 | Agbeyewo ise saa keji Iori Edé, Äså ati Litirésö Yorübå | Agbeyewo ise saa keji Iori Edé, Äså ati Litirésö Yorübå |
| 13 | Idänwd såå keji | Idänwo såå keji |
Primary 4 Third Term Scheme of Work for Yoruba Language
| CLASS | Primary/Basic 4 | |
| SUBJECT | Yoruba | |
| TERM | Third Term | |
| WEEK | TOPICS | Learning Objectives |
| 1Ede | Idanwo ranpe fun ibeere saa tuntun | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i.Gbaradi fun ise saå tuntun ii. Ranti åwon eko ti won ti ko ni såå o koja |
| Asa | Atunyewo eko lori asa | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Rånti gbogbo imö åti eko ateyinwa |
| Lit | Atunyewo eko nipa literaso | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Råntå gbogbo imö ati åteyinwa. ii. Nå imö kikun iii. Dahun ibeéré Iori ohunti won ko |
| 2Ede | Onkà Yorûbâ – Ogorun-un – Ââdojo (100-150) | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Sàlàyé ilàna ti a n gbà ka ònkà Yorubâ: ii. Ilana ilopo iii.llana aropo iv. Ilana ayokürò v. Ka onka lati ogôrûn-un de aadojo |
| Asa | Orikì Orilë ati itumo re | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Sàlàyé ohun orikì orilë jê ii. Darüko orisìi orikì orilë kòokan iii. jiròrò nipa koko ti o je yo ninü orikì orilë. iv. Sàpèjuwe ìyàto Iaàrin oriki orile kan si ìkeji. |
| Lit | itan Akoni: Balogun ibikunlé | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i.Salayé nipa ìtan igbési ayé Balogun ibikünlé ii. Darüko ìlü ti ati bi Balogun ibikünlé iii. So nipa ișę rere ti okunrin naâ șe, |
| 3Ede | Ônkâ Yoruba: aadojo dă igba (150-200) | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Ka Ônkâ lăti aadojo de igba (150-200) Îi. SâIâye bi a șe Io âmi Îsędipupo, ayokuro âti âșopo iii. llânâ onkâ âdăyeba âti ode-oni. |
| Asa | Âwon ohun ti o un farahân ninu oriki orîlë | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Sâlâye ki ni oriki orilë. ii.Dâruko oriki orilë âti iran kookan iii. Răntî âwon ohun ti ri fojóhân nînu âwon oriki orilë iv. menuba pataki ati i owulo oriki onile |
| Lit | Itan Akoni Herbert Macauly | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Sâlâye ‘ltân igbosi aye akoni yii ii. Oodun ti a bi Herbert Macauly iii. Sàlàyé àwon ise rere ti o se iv. jiroro nipa awon ohun ti o so arakunrin naà di akoni. |
| 4Ede | Oro Oruko | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. fun oro oruko ni orikì ii. Sàlàye ëya oro orüko bi àpeere: Âridìmü, afòyemò, aseeka, alafiseeka, orüko ibìkan, abbi. iii. Ko apeere oro orüko kòkan iv. Menuba abùdâ oro orüko àti ise won |
| Asa | Kiki Oriki Orile | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Ki orikì onile ìran kookan ii. Sàlàyé koko tô joyo ninu orikì kookan iii. So nipa ìtan to ro mo orikì kookan iv. Toka si eewo iran kookan v. So nipa ibi ti iran naa |
| Lit | Itan Akoni Ransome Kuti | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Sålåyé itån Igbési aye akoni yii ii.odün ti abi Ransome Kuti iii. Sålåye awon ise rere ti o se iv. jiroro nipa awon ohun ti o so arakunrin nåå di akoni. |
| 5Ede | Oro Orüko – Ise ti oro oruko n se ninu gb0lohün | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Ki eéki oro orüko ii. Sålåyé ise ti orö oruko n se ninu gbolohun . B.A. Olüwå, Äbo ati eyån iii. Pin oro oruko si isori iv. Ko oro orüko sile |
| Asa | Eewo ti aisan mü wa | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i, Sålåyé ki ni ééwo ii. Dåruko orisi eewo to wa iii. Salaye Ohun to sokunfå eewo wonyi iv. Pin eewo si isori eewo alian, eewo Imototo, eewo ise, eewo Iran / Idile v. Dåhün beere lori eko |
| Lit | Itan Akoni -Obafemi Äwolowö | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i, Se åpéjüwe Oloyé Qbåfémi Awolowö ii. So nipa itån Igbesi ayé 0loyé Obåfémi Awdlowo iii. Sålåyé ise ribiribi ti okünrin naå nigbå aye re eyi ti o so o di akoni. |
| 6Ede | Fifa orö oriko yo ninu gbolohun édé Yorüba | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Da örö oruko mo ninü gbolohün ii. Såpéjüwe orisi orö oruko iii. Toka si ise ti oro oruko o se nini gbolohün |
| Asa | Itumo to o ro mo eewo kookan | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Sålåye åwon ééwo ti aisan mu wa ii. So nipa ééwö ti o jemo ise kookan iii. Se åkojo éewo lorisirisi iv. Daruko eewo fun ìlera titi Imototo |
| Lit | Itan Akoni Mosudi Olawale Abiola | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Se àpèjüwe Mosüdì Olawâlé Abiolâ ii. So ìtàn ìgbési ayé Môsüdì Abiola MKO iii. Salaye awon isê ribiribi té se nigbà ayé re iv. Ya àwòrén MKO Âbiola. |
| 7 | Idanwo Ranpe/lbewo/Olidè ìdaji saa | Idanwo Ranpe/lbewo/Olidè ìdaji saa |
| 8Ede | Aroko Oniroyin | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. ki oriki aroko oniroyìn ii. Sàlayé ìlànà kiko aroko oniroyìn -Ifaara, àlayé, ìgunle, abbl. iii. Ko aroko oniroyìn Iori koko oloro kan |
| Asa | Eewo ti aisan | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Salaye lori ewo aisan ati idi to o fin je eewo ii. Tunmo awon eewo wonyi iii. Daruko awon eewo ti aisan mu wa |
| LIt | Itan Aboni-Moremi | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Sàpèjuwe Morèmi Ajasoro bi Aboni ii. Salàyé itan igbesi aye re iii. So nipa ise ribiribi to se nigba aye re |
| 9Ede | Aroko Asapejuwe | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Ki oriki aroko asapejuwe ii. Salaye ilana kiko aroko asapejuwe -ifaara, afaye, igunle, abbi |
| Asa | Anfant ti o wa nibi Pipa ééwo mo | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Salaye anfani ti o wa ni bi papa eewo mo ii. Daruko awon eewo ile yoruba ati ohun ti o ro mo ewo na iii. So pataki pipa eewo mo |
| Lit | ltån Aboni – Efunroyé Tinubu | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Såpejuwe aboni obinrin – Efunroyé Tinubu ii. So nipa Itan Igbési ayé re iii. Toka si ise ribiribri to se nigbå aye re -Ya åworan Efunroyé Tinubu |
| 10Ede | Äroko Asåriyånjiyån | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Ki oriki eewo asariyanyin ii. Salaye ilana kiko aroko asariyanjiyan – ifara, alaye, igunle abbi iii. Ko aroko asariyanjiyan lori koko oro kan |
| ASa | Ééwö Iran/ilu | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Salaye eewo ilran ati ilu kookan ii. Såläyé okünfai ééwö naä iii. So iyipadå to dé bå eewo yi |
| Lit | Itesiwaju Itan Aboni- Funmilayo Kuti | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Såpéjåwe aboni Obirin Funmilayo Kuti ii. So nipa Itan Igbési ayé re iii. T’ oka si ise ribiribri to se nigba aye re -Ya aworan Funmilayo Kuti |
| 11Ede | Eya Ara Fifo | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. ki eéki eyå ara ifo ii. dåruko åwon eya ara ifo tö wå fun iro édé pipe iii. pin eyå ara ifö si åsunsi ati akanmole |
| Asa | Kiki Oriki Ilu bii Ife, Ékiti, Éko abbl. | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. ki oriki åwon bii Öyo, Ékitl, Éko, abbi. ii. Salaye awonh koko inu oriki naa iii. Jirorö nipa åbüdå ilü koökan |
| Lit | Itan Aboni – Klidlråtü Abiola | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Sapejuwe aboni obinrin Kudiråtu Abiölå ii. So nipa Itan igbési aye re iii. T oka si ise ribiribri to nigbå aye re -Ya aworan Kudiratu |
| 12 | Ałunyewo ęko lori ișë saâ ninu Ëdë, Âșâ âti litłreșo | Ałunyewo ęko lori ișë saâ ninu Ëdë, Âșâ âti litłreșo |
| 13 | Akanșe idanwo lori ișę odun yii ninu Ëde, Âșâ âtl litłreșo | Akanșe idanwo lori ișę odun yii ninu Ëde, Âșâ âtl litłreșo |
